[Audio] Odun Aluyo By Bukola Eshorun
Nigeria Gospel Artists, Songwriter and anointed Worship Leader, Bukola Eshorun is out with a new song “Odun Aluyo” off his latest released album titled “Odun Aluyo”
Odun Aluyo was produced by Abbey Mix, stream and download below while not forgetting to share with your friends.
Odun Aluyo – Lyrics:
Odun aluyo to de o
Odun Ominira leyi funmi
Oun gbogbo lotun lotun
Ileri ati majemu da muse
Emi ti pon ninu kanga iye lodun yi, moti laluyo
Aseyori lori irin ajo mi
Aseyori lori Idawole mi
Aseyori Lori Ile mi
Aseyori Lori Ise mi
Aseyori Lori Omo mi, Ni mo bere fun
(Instrumental)
(Odun Aluyi tide o….)
Itesi waju lori ise, Oko mi
Ni mo un toro o, Kaye bami yo, kan bami dupe
Ko dun yi to pari o
Kodun yi to pari
(Odun Aluyo tide o….0
Oun ti mo ba dawole o ti yori si rere/2ce
O ma yori si rere Ninu Odun ti mo wayi o Mo ti laluyo
Emi ti laluyo Mo ti laluyo
Se iwo ti laluyo Mo ti laluyo
Awa ti laluyo Mo ti laluyo
Ninu odun ti mo wayi o Mo ti laluyo
Baba ti nu omije mi nu
Owa so ekun mi de rin fun mi
Egan aiye mi ti de ogo, Odi jerich aye mi wo lule
Aseyori wa je titemi Mo ti da segun
Emi ti da segun Mo ti da segun
Se iwo ti da segun Mo ti da segun
Ninu Odun ti mo wayi o Mo ti da segun
Emi ti laluyo Mo ti da segun
Se iwo ti laluyo Mo ti da segun
Awa ti laluyo Mo ti da segun
Onise Iyanu ti se o, Oti fi aye mi se Iyanu
Omije mi ti de ogo, Orin Isegun je titemi
Aseti ti dopin, Idamu ti dopin
Ida duro ti dopin, Odun Igbega mi layi je
Oro eri lenu mi, Lodun yi ma kore oko dele
Ile mi asan fun wara ati oyin
Baba ti de mi lade
Emi ti laluyo Moti Laluyo /2ce
Se iwo ti laluyo Mo ti laluyo
Awa ti laluyo Moti laluyo
Ninu Odun ti mo wayi o Moti laluyo
Sister seti laluyo Moti laluyo
Brother seti laluyo Moti laluyo
Awa ti Laluyo Moti laluyo
Ninu odun ti mo wayi o Moti laluyo
Call/Res: Ire mi Kaye Mafi dun mi o/2ce
Baba dahun Soro mi kaye mafi mise yeye
Larin egbe mi baba jeki laluyo
Ninu ebu m semi lologo omo
Tebi tara mi jeki un ki mi ku ori ire
Omo ologo sha lemi je kan rawo ogo lara mi
Kodun yi to pari je kan wa bami gbegba Ope
Ninu Odun yi baba jeki laluyo
Pamilerin ayo o ninu odun yi
Ire mi jaye mafi dun mi o
Ire mi baba mafi dun mi o
Ninu odun yi baba jeki laluyo.